BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Kí ni nǹkan tí àwọn èèyàn tó fẹ́ kú máa ń rí lásìkò tí wọ́n bá fẹ́ kú?
Kerr sọ fún BBC News Brasil pé ọ̀pọ̀ àwọn tó bá ń pọ̀kàkà ikú ló máa ń rí àwọn tí wọ́n ti jọ ní àjọṣepọ̀ rí, tí wọn yóò sì tún jọ máa ṣe lọ́nà tí yóò mú àláfíà bá ọkàn wọn.
Wo ìdí tí ìjọba yóò ṣe máa fi ọlọ́pàá gbé àwọn olókòwò POS kan
Ni ọjọ Aje to kọja ni ijọba kede pe gbogbo awọn olokowo POS gbọdọ forukọsilẹ pẹlu alakalẹ banki apapọ Naijiria, CBN.
Àwọn aṣòfin l’Abuja tako àbá fún ìdádúró 0.5% owó orí táwọn báńkì fẹ́ máa yọ lórí àwọn oníbàárà
Lati igba ti CBN ti ṣe ikede yii lawọn eeyan ti n fi aidunnu wọn han lori igbesẹ ijọba yii.
Níbo ni Mukaila Lamidi 'Auxiliary', alága ẹgbẹ́ awakọ̀ èrò tẹ́lẹ̀ nípínlẹ̀ Oyo wà?
Ti ẹ o ba gbagbe, ni bi oṣu meloo kan sẹyin ni ileeṣẹ ọlọpaa kede wi pe awọn n wa Auxiliary.
Fásitì BOUESTI jáwè ẹ lọ gbélé yín fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó na akẹgbẹ́ wọn, ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí
A gbọ pe akẹkọọ imọ Mass Communicaiton ni gbogbo awọn akẹkọọ naa jẹ.
Alága ìjọba ìbílẹ̀ fi ògún búra fún àwọn èèyàn tó yàn sípò
Iroyin sọ pe alaga naa ṣe ibura fun awọn to ṣẹṣẹ yan sipo pẹlu ada ati Bibeli pẹlu Kuran.
Ṣé lóòtọ́ọ́ ni Opay fẹ́ kógbá wọlé ní Nàìjíríà?
Lati igba ti banki apapọ CBN ti paṣẹ pe ki Opay atawọn ile ifowopamọ ori ayelujara mii dawọ gbigba onibaara tuntun duro ni ọpọ eeyan ti n gbe oriṣiiriṣii iroyin kiri nipa Opay.
Wo àtúpalẹ̀ orílẹ̀èdè Togo lábẹ́ ìjọba ìdílé Gnassingbé
Ni bayii ti Faure Gnassingbé n gbe igbese lati ṣatunse si ofin ti yoo mu ko tun tẹsiwaju lori oye, araalu ti n yari.
Àǹfàní wo ní fún aráàlú, bí Nàìjíríà bá dín iná mọ̀nàmọ́ná tó ń pèsè fáwọn orílẹ̀èdè mìíràn kù?
NERC ní láti ọjọ́ Kìíní, oṣù Karùn-ún títí di oṣù Kẹwàá ọdún 2024, ìdá mẹ́fà nínú ìdá ọgọ́rùn-ún iná mọ̀nàmọ́ná tí àwọn iléeṣẹ́ náà ń pèsè ni kí wọ́n máa fún àwọn orílẹ̀ èdè mẹ́tẹ̀ẹ̀ta.
Ìjà Awolowo, Akintola àti ogun 'Wẹtiẹ', ẹ̀kọ́ wo ló kọ́ wa?
BBC Yoruba ṣe àtúpalẹ̀ ohun tó fa ìjà láàrin Obafemi Awolowo, Ladoke Akintola èyí tó bí ogun Wẹ́tiẹ̀ àti Ìṣubú ìjọba alágbádá àkọ́kọ́, àti ẹ̀kọ́ to wà nínú rẹ̀ fún ìjọba alágbádá kẹrin.
Ìjọba àpapọ̀ fòfin de abẹ́rẹ́ tí wọ́n kó wọlé láti òkè òkun láwọn ilé ìwòsàn Nàìjíríà
Ijọba ti wa paṣẹ fun gbogbo awọn adari ile iwosan, CMDs ati MDs lati maa ra abẹrẹ ti wọn ṣe ni Naijiria ni
Aráàlú dín dùndú ìyà fún òṣìṣẹ́ FRSC lẹ́yìn tí wọ́n ní ó ṣokùnfà ìjàmbá ọkọ̀ n'Ibadan
A gbọ pe ni kete ti awọn ọlọpaa to maa n ṣe ayẹwọ ọkọ lagbegbe naa ri ohun to n ṣẹlẹ lawọn naa ba ẹsẹ wọn sọrọ.
Ìròyìn Àkàgbádùn
Àwọn àǹfàní àti àléébù wo ló wà nínú fífi owó kún owó òṣìṣẹ́?
Pẹ̀lú bí àwọn nǹkan ṣe ń gbówó lórí yìí, àwọn onímọ̀ sọ pé ìjọba nílò láti rí pé wọ́n pèsè àwọn ohun amáyédẹrùn kan kí owó tí wọ́n bá máa fi kún owó òṣìṣẹ́ le ní ìtumọ̀.
Awuyewuye lórí ìgbéyàwó Taiwo Cole, ìyàwó Wofai ní òòyà ò le ya àwọn, ẹbí ọkọ 'fàáké kọ́rí'
Lẹyin ti fọto igbeyawo Taiwo ati Wofai lu ori ayelujara pa tan lọjọ Aiku ọjọ karun un oṣu Karun un ni ẹbi Cole fi atẹjade kan sita ninu eyi ti wọn ti sọ pe awọn ko fọwọ si igbeyawo laarin awọn mejeeji.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ṣàlàyé ìdí tó fi fẹ́ wó ọgọ́rùn-ún ilé abẹ́ afárá Adeniji Adele lónìí
Kọmiṣọna fun ọrọ eto ayika ati alumọni inu omi nipinlẹ Eko, Tokunbo Wahab lo fọrọ yii lede loju opo X rẹ.
Hamas ṣetán láti dáwọ́ ogun dúró lẹ́yìn tí Israel pinnu láti ṣe ìkọlù sí ìlú Rafah
Netanyahu ni ko si ohun ti yoo yẹ ikọlu naa bo tilẹ jẹ pe ọrọ ajọsọ lati lati dawo ogun duro n waye laarin rẹ ati ẹgbẹ ọmọ ogun Hamas.
Iléeṣẹ́ iná mọ́nàmọ́ná kéde àdínkù owó ìná ẹ̀lẹ́ńtíríkì
Ọpọlọpọ ariwo lo ti n waye lori afikun owo ina mọnamọna ti ijọba apapọ orilẹede Naijiria kede loṣu diẹ sẹyin.
Ọmọọba Harry àti Meghan Markle fẹ́ ṣàbẹ̀wò sí Naijiria l’oṣu karun-un
Invictus Games ni idije ere idaraya ti wọn ṣagbekalẹ rẹ fawọn oṣiṣẹ ologun ati agbofinro ti wọn farapa loju ogun, lati maa fi dun wọn ninu.
Ìjọba fáwọn olùgbé ilé àkọ́patì Ikoyi Tower l'Eko lọ́jọ́ méjì láti kúrò níbẹ̀, bí bẹ́ẹ̀ kọ̀ọ́...
Kọmiṣọna fọrọ eto ayika ati ọrọ omi nipinlẹ naa, Tokunbọ Wahab lo sọ eyi di mimọ lasiko to ṣe abẹwo si agbegbe naa, nibi ti awọn eeyan n sun si lai gba aṣẹ.
Wo bí àṣírí ọ̀gá bánkì tó rí ẹ̀wọn ọdún mọ́kànlélọ́gọ́fà he lórí ẹ̀sùn jìbìtì N112m ṣe tú
Adajọ S. N. Odili gbe idajọ naa kalẹ lẹyin to ni awọn ẹri toun ri gba lori ẹsun ti wọn fi kan Placidus kọja ohun ti wọn le dawọ bo mọlẹ.
Akẹ́kọ̀ọ́ Kwara méjì fakọyọ nínú ìdánwò JAMB, gba máàkì 358 àti 362
Akekọọ ile ẹkọ girama ipinlẹ Kwara wa lara awọn akẹkọọ to fakọyọ julọ ninu idanwo JAMB ọdun 2024.
Àwọn ọ̀dọ́ bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn l’Osun lórí ọ̀wọ́ngógó epo, iná mọ̀nàmọ́ná àti oúnjẹ
Iwọde naa lo waye niluu Osogbo nipinlẹ Osun.
Agbẹjọ́rò wọ́ Adelabu àtàwọn míì lọ sílé ẹjọ́ fẹ́sùn pínpín iná mọ̀nàmọ́ná sí ìsọ́rí
Àwọn mìíràn tí Akingbolu tún pé lẹ́jọ́ ni àjọ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ iná mọ̀nàmọ́ná Nàìjíríà, Nigeria Electricity Regulatory Commission (NERC) àti Ikeja Electricity Distribution Company (IKEDC).
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Móríwú
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Àwọn nǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa ètò ìdìbò ààrẹ tó bẹ̀rẹ̀ ní Chad
Olùdíje ogún ló fi ìwé ẹ̀rí wọn kalẹ̀ síwájú ìgbìmọ̀ tó ń rí sí ètò ìdìbò èyí tó wáyé láàárín ọjọ́ Kẹfà sí ọjọ́ Kẹẹ̀dógún, oṣù Kẹta fún àyẹ̀wò.
Wo ìdí tí ẹni tí ipò Olubadan kàn fi ṣàbẹ̀wò sílé Olubadan àná
Osi Balogun ṣalaye pe igba akọkọ ree ti ẹni ti oye Olubadan kan yoo ṣe abẹwo si ile Olubadan to gbeṣe niluu Ibadan.
Ṣé lóòtọ́ọ́ ni ìjọba ìpínlẹ̀ Eko dá àwọn olùgbé ìlú Eko kan padà sí ìpínlẹ̀ wọn l'Osun?
Iroyin naa to lu ori ayelujara pa sọ pe ni ṣe lawọn ọlọpaa sa awọn ọdọ kaakiri lawọn oju popo kan niluu Eko ti wọn si fi ọkọ akero nla ko wọn pada si ipinlẹ Osun.
Ìjà parí! Ogogo àti Yinka Quadri dìmọ́ ara wọn lẹ́yìn tí Ajobiewe báwọn dá si
Ṣáájú ni àwọn ìròyìn kan ti ń lọ lórí ayélujára pé nǹkan kò lọ déédé láàárín àwọn àgbà òṣèré méjéèjì láti ọdún tó kọjá àmọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn ni kò gbàgbọ́.
Sola Sobowale ṣàlàyé bí ó ṣe rìn ìrìnàjo láti ayé 'Toyin Tomato' lọ ṣé 'Caregiver' ni London
Ilumọka oṣere, ẹni ọdun mejidinlọgọta tan imọlẹ si awọn iṣẹlẹ yii lasiko to n ṣe ifọrọwerọ lori eto Teju Baby Face lọjọ Isẹgun.
Iléeṣẹ́ O Pay ti dá a padà fún CBN, wọ́n si bá àwon Oníbàárà wọn sọ̀rọ̀ pé...
Àwọn ilé iṣẹ́ bíi Opay, Kuda Bank, Palmpay àti Moniepoint ni ọ̀rọ̀ náà kàn, tí wọn kò ní ní àǹfàní láti gba àwọn oníbàárà tuntun láàyè láti ṣí akoto owó pẹ̀lú wọn fún ìgbà kan ná.
Kí ló fa gbas-gbos láàrin Davido àti Wizkid lórí ayélujára?
Ori itakun ayelujara X ni rogbodiyan naa ti waye lopin ọsẹ.
Wo ohun tí àwọn aráàlú ń là kọjá nítorí àìrí epo bẹntiróòlù rà lónìí
Bo tilẹ jẹ pe ajọ NNPCL to n ri si ọrọ epo rọbi sọ lopin ọsẹ wi pe awọn ni epo to to ọmọ Naijiria lo ni ipamọ, alukoro ẹgbẹ IPMAN, Ọgbẹni Chinedu Ukadike ti fidi rẹ mulẹ pe ko si epo to to araalu lo ni Naijiria lọwọ yii.
Wo àwọn nǹkan méje tí o kò mọ̀ nípa Egbin Orun, akọrin ẹ̀mí tó dolóògbé
Olorin ẹmi bii tiẹ, Esther Igbẹkẹle, lo fi iroyin iku naa soju opo Instagram rẹ lọjọ Satide, ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣu kẹrin yii.
'Ìbejì ni wá ṣùgbọ́n àyẹ̀wò DNA ní bàbá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló bí wa'
Awọn onimọ sayensi ṣalaye pe, iru iṣẹlẹ yii ṣọwọn, ti ko si ju mẹwa lọ to ni akọsilẹ lagbaye ṣugbọn o wọpọ laarin ẹranko.